blogygold

New definition of online Magazine and Services: Designs | Trainings | Solutions | Consultancy Magazine for creative people, photographers painters, interesting stories and enthusiastic seekers. A place for write and share stories and earn money by doing so. Are you interested ? If so, blogygold could be the place for you. Click login and join us now

1,471 Views

Iponju Re Fere (Your affliction is light) Mp3 By Taiwo Akinrefon

Nigerian Gospel Minister, Taiwo Akinrefon has come through again with another song from the realm of the spirit titled “Iponju rẹ fere” Your affliction is light.

Kindly make sure to download listen and share with friends.

Have you been looking for the best platform to download the latest Naija music? You are in the right place?


This track is an amazing track if you are a lover of music, feel free to get yours direct to your playlist from our platform. 


Listen & download it below

DOWNLOAD

IPỌNJU RE FERE (YOUR AFFLICTION IS LIGHT) LYRICS

All:
Ipọnju re fere, ore mi o
Gbekele Jesu aba ọ ṣe laipe
Ijiya isisinyi koto lati fi sakawe ogo o
Tao fihan ninu wa
Your breakthrough is at hand.

Repeat All:
Ipọnju re fere, ore mi o
Gbekele Jesu aba ọ ṣe laipe
Ijiya isisinyi koto lati fi sakawe ogo o
Tao fihan ninu wa
Your breakthrough is at hand.


Verse1. Ki wura to dan o
Oti la ina koja o
Isoro ayé rẹ
Lati so e dalagbara ni
What you are passing through
The Lord knows about it
It is a matter of time
Your testimony is at hand.

Chorus: Ipọnju re fere, ore mi o
Gbekele Jesu aba ọ ṣe laipe
Ijiya isisinyi koto lati fi sakawe ogo o
Tao fihan ninu wa
your breakthrough is at hand.

Verse 2
Ireti wa fun’gi ta belori toba gboorun omi a so
P’oosi wa laye too tiku
Ireti nbe fún ọ o odaju
Eni temi bati bo lenure ni kosi ireti fún mọn rara
B’aoku ise kotan o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ.

Chorus: Ipọnju re fere, ore mi o
Gbekele Jesu aba ọ ṣe laipe
Ijiya isisinyi koto lati fi sakawe ogo o
Tao fihan ninu wa
your breakthrough is at hand.

Verse3.

Pupo pupo ni’ponju olododo ṣugbọn Oluwa gba ninu rẹ
Ọlọrun to da o ko gbagbe re
He has you in his mind
Iwo sati gbekele oluwa
Ooni jogun ofo layelaye
B’ekun ba pe dalekan o
Ayo nbọ lowuro

Chorus:
Ipọnju re fere, ore mi o
Gbekele Jesu aba ọ ṣe laipe
Ijiya isisinyi koto lati fi sakawe ogo o
tao fihan ninu wa
Your breakthrough is at hand.

Call:
Iwo sati gbagbo
Iwo sati gbekele
Iwo sati gbagbo o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ

All:
Iwo sati gbagbo
Iwo sati gbekele
Iwo sati gbagbo o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ

Call: Oun w’oju Oluwa f’ọmọ
Òun w’oju Oluwa f’aya
Òun w’oju Oluwa f’ọkọ o
Laipe laijina won a to e lọwọ

Response:
Iwo sati gbagbo
Iwo sati gbekele
Iwo sati gbagbo o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ

Call: Ise gidi loun fe
Ile tiẹ lo fe kọ́
Landlord tile e sita
Iwo sati gbagbo o
Laipe laijina won a ki e ku oriire

Response: Iwo sati gbagbo
Iwo sati gbekele
Iwo sati gbagbo o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ

Call:
Admission l’oun wa
Igbega l’oun fẹ
Abi o fe lo s’ilu oyinbo
Iwo sati gbagbo o
Your testimony is at hand.

Response:

Iwo sati gbagbo
Iwo sati gbekele
Iwo sati gbagbo o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ.

Call:
Boya oti je gbese lo rẹpẹtẹ
Oti je gbese lo jaburata
Ọlọrun to san gbese opo wọnni
A san gbese rẹ.

Response:

Iwo sati gbagbo
Iwo sati gbekele
Iwo sati gbagbo o
Ọrọ rẹ nbọ wa d’ayọ.

Call: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ

Call: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ


Call: Mabo’kan je rara Oluwa a ṣe
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Ogun t’ole koko oun bo waasẹ
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Ẹkun osoosu yen a digbagbe pata
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Kas’ise bi erin je’je eliri a tan
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Kosi koto koka gbogbo è ló máa dopin
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Gbogbo oun t’oofe pata ni baba a yanju
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Mase sáré mọto kolu keke
Response: Oro rẹ nbọ wa d’ayọ
Call: Opo Jesu ni koo dimun o
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: Aba nise ni kiidoju tini
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ
Call: B’ekun pe dale kan ayo nbọ o
Response: Ọrọ rẹ n bọ wa d’ayọ.

Leave a Reply